Ṣèbí oun tí mo mọ̀n tí wọ́n má ń sọ ni pé òkùnkùn kìí bórí ìmọ́lẹ̀, pé irọ́ kìí jáwé borí òtítọ́, pé rìkíṣí kìí…
Aáyan ògbufọ̀ Sùúrù (Orin Démíanù ọmọ Málì àti Ọba Náàsì) Patience (ft. Nas)Damian Marley Ẹsẹ̀ Kiní …
Ènìyàn Ènìyàn o, Ènìyàn yán Ènìyàn a b’ìdí yàn àn yán o Ènìyàn Òṣèlú, Ènìyàn ọ̀jẹ̀lú Ènìyàn tí ń f’agbáda gba agbada alágbẹ̀dẹ Ènìyàn tí…
Inú wá dùn púpọ̀ láti kéde àtẹ̀jáde gidi ìwé wá —Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé. Iye: Ẹgbẹ̀rún Méjì àtààbọ̀ (N2,500) Ìfiṣọwọ́: Ọ̀fẹ́ ni a ó bá yín gbé…