Inú wá dùn púpọ̀ láti kéde àtẹ̀jáde gidi ìwé wá —Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé.
Iye: Ẹgbẹ̀rún Méjì àtààbọ̀ (N2,500)
Ìfiṣọwọ́: Ọ̀fẹ́ ni a ó bá yín gbé ìwé náà dé ilé ìfìwéránṣẹ́ (post office) tó sún mọ́ ń yín jùlọ.

Bí ẹ ṣe lè sánwó

Ẹ tiransifa owó náà sí àkántì yìí :
Orúkọ Bánkì: First Bank Plc
Orúkọ Àkántì: Oredola Ibrahim
Nọ́mbà Àkántì: 3047635789
Lẹ́yìn èyí, ẹ ó wá fi àwọn wọ̀nyí ránṣẹ́ sí wa ní orí ẹ̀rọ ìfìwéránṣẹ́ ayélujára ibeere@atelewo.org tàbí kí ẹ fi ṣọwọ́ sí orí wásápù 07061282516:
– Ẹ̀rí owó tẹ́ẹsan
– Àdírẹ́sì yín
Àbí ìwé orí afẹ́fẹ́ rẹ̀ ni ẹ̀yin fẹ́? Ẹ yẹ bí wò.
————————————————————————————————–
We’re very excited to announce that you can now order for your hardcopy of our book—Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé.
Price: 2, 500
Delivery: Free delivery to your nearest post office.

Method of payment

Make a transfer to the account details below:
Bank Name: First Bank Plc
Account Name: Oredola Ibrahim
Account Number: 3047635789
Afterwards send the following details to ibeere@atelewo.org
Or on whatsapp to 07061282516 :
– Evidence of Payment
– Your address
You want a soft copy instead? Check this link.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *