OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà àkìrẹ́líkì fẹ́lẹ́, kẹrosínì, fún àdìrẹ táì àti dáì- aidurosọ́fáitì, kọ́sítiki sódà, pẹ̀lú okun ráfíà.

ÀKỌ́LÉ :onílù

OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà àkìrẹ́líkì

ỌDÚN : 2018

ORÚKỌ AYÀWÒRÁN:  Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá

SÍTÁILÌ: Araism (iṣẹ́ ọnà).

ÀKỌ́LÉ :Agbè Ẹmu

OHUN ÈLÒ : Òwú sílíkì.

ỌDÚN : 2017 ni iṣẹ́ bẹ̀rẹ̀ l’órí rẹ̀

ORÚKỌ AYÀWÒRÁN:  Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá

GBÓLÓHÙN NÍPA IṢẸ́ NÀÀ

Kèrègbè ẹmu jẹ́ ohun tí a ń fi gba ẹmu sí. Ohun tí ẹmu ń ṣe l’ára dára púpọ̀. Ìkiní ni fún ìwòsàn ara. Ìkèjì, o ń fún ara lókun. Bẹẹna ẹmu mímu wúlò o sì tún dára fún ìwúre lọ́dọ̀ àwọn àgbàlagbà nílẹ̀ Yorùbá. Oríṣiríṣi ìkòkò l’ówà lẹ́yìn iṣẹ́ ọnà naa, ìdí tí mo fi wu lorisirisi ni wípé a ni oríṣi ìkòkò ní ilẹ̀ Yorùbá. Gbogbo rẹ̀ ló wúlò fún omi pípọn nílẹ̀ Yorùbá.


Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá. Abi sí ilu Igbóọràkan ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ijọba ìbílẹ̀ ìbàràpá. Ó ṣetán ní fáfitì Ifẹ̀ (Ọbafẹ́mi Awólọ́wọ̀ University) ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun. Iṣẹ́ ayàwòrán ni ó yàn láàyò, bi iṣẹ́ ọnà (embroidery/craftwork), Àwòrán (portrait) àti pípa aṣọ láró (táì, dáì àti bàtíkì). Gbogbo rẹ̀ lóni ìbátan lórí iṣẹ́ ayàwòrán. Ẹ kàn si Fèyí ni orí ago +234 705 827 3046.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *