Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death
Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì jẹ́ àlá? Kí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ayọ̀ náà kọja lọ bí ẹ̀mí tó dòkú? Àwọn ìgbádùn ìgbà díẹ̀ fẹ́rẹ̀ dàbí ìran. Síbẹ̀síbẹ̀ a rò pé ìrora ńlá jùlọ ni láti kú II. Ìyàlẹ́nu ni èyí jẹ́ bí ènìyàn orílẹ̀-ayé ṣe ní láti máa rìn kiri, Tí ó sì gbé ìgbé ayé ìbánújẹ́, ṣùgbọ́n tí kò káàárẹ̀ Ipa ọ̀nà rẹ̀ yìí ṣòro, bẹ́ẹ̀ kò le nìkàn rìǹ-ín. Ọjọ́ ọ wájú rẹ̀ ti kú ṣùgbọ́n tí ó yẹ kí ó wà láàyè.
On Death
On Death I. Can death be sleep, when life is but a dream, And scenes of bliss pass as a phantom by? The transient pleasures as a vision seem, And yet we think the greatest pain's to die. II. How strange it is that man on earth should roam, And lead a life of woe, but not forsake His rugged path; nor dare he view alone His future doom which is but to awake. ~John Keats (short peom)
Nípa Olùtúmọ̀:
Olúwáfẹ́mi Kẹ́hìndé jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, tí a bí ní ìlú Ìbàdàn. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè B.A nínu ẹ̀kọ́ Ìmọ̀ Ẹ̀dá Èdè àti Èdè Yorùbá ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásitì Adékúnlé Ajásin Àkùngbá Àkókó. Ònkọ̀wé ni, ó sì fẹ́ràn Èdè àti Àṣà Yorùbá gidi gan.
Àwòrán ojú ìwé yìí jẹ́ ti Nigeria Culture art image https://www.google.com/search?q=Nigeria+Culture+image+on+death&client=ms-opera-mini-android&channel=new&sxsrf=ALiCzsbo2wW2zpOUIAb9VWWsMqOmSJJz2w:1671801987171&source=lnms&tbm=isch&sa=X&ved=0ahUKEwjyxdHc64_8AhX2i_0HHaVVCnQQ_AUIBigB&biw=412&bih=658#imgrc=xEbr40oqrifKqM