Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Tags archive: pelebe

Home /Tag:pelebe
Àṣàyàn Olóòtú

Ìlànà fún Ìgbàwọlé: Àtẹ̀jáde Àtẹ́lẹwọ́ Apá kejì

October 3, 2019 0

A dúpẹ́ fún àwọn ohun tí ẹ fi ṣowọ́ sí wa fun àtẹ̀jade Kínní. Àtẹ̀jade kejì yíò jẹ́ ìfisorí fún àwọn àgbà oǹkọ̀wé mẹ́ta tí…

Aáyan ògbufọ̀

Sùúrù (Orin Démíanù ọmọ Málì àti Ọba Náàsì) | Ọ̀rẹ́dọlá Ibrahim

November 18, 2018 0

  Aáyan ògbufọ̀  Sùúrù (Orin Démíanù ọmọ Málì àti Ọba Náàsì)      Patience (ft. Nas)Damian Marley                  Ẹsẹ̀ Kiní                                        …

Ìròyìn

Ra ìwé Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé / Buy Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé Hardcopy Book

April 11, 2018 0

Inú wá dùn púpọ̀ láti kéde àtẹ̀jáde gidi ìwé wá —Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé. Iye: Ẹgbẹ̀rún Méjì àtààbọ̀ (N2,500) Ìfiṣọwọ́: Ọ̀fẹ́ ni a ó bá yín gbé…

Ìròyìn

ÀTẸ́LẸWỌ PÉLÉBÉ TI JÁDE/ ÀTẸ́LẸWỌ PÉLÉBÉ IS OUT!

February 8, 2018 0

Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù ló yọ Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù ló yọ Àṣẹ̀ṣẹ̀dé ọṣù, wọ́n lo ṣ’ara bíntín Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù…

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Orin
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized