Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…
Ọmọ mí Mo bá wọn ná'jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́ tó sọnù Mo wẹ'dò mẹ́fà,…
Bí mo ṣe gbọ́ ìbéérè tí Dádì béèrè lọ́wọ́ mi, ṣe ni mo fi ẹ̀rín tó fẹ́ wú jáde lẹ́nu mi pamọ́ sí ẹ̀rẹ̀kẹ́. Ṣè…
Ṣèbí oun tí mo mọ̀n tí wọ́n má ń sọ ni pé òkùnkùn kìí bórí ìmọ́lẹ̀, pé irọ́ kìí jáwé borí òtítọ́, pé rìkíṣí kìí…
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí ìwọgan an wá di ẹni…
Wón ní, Ikú ogun ló ń pa akíkanjú Ikú odò lo ń p’òmùwẹ̀ Ikú ẹwà ni wón ní ó ń pa egbin Ikú abo ló…