Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì mi ló sọ wípé, Kí…
Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà mí ni mo ṣe kọ…
Ọdún tí ọwọ́ tẹ Ẹ́fáansì ajínigbé Ọjọ́bọ̀. Ọjọ́ kẹ̀jọ, Oṣù Agẹmọ. Gbogbo bí wọ́n ṣe nkígbe níle Kejì, hun ò kúkú yọjú. Wọ́n ni àgbà…