Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra, ó di dúnníyàn Mo wá…
Ènìyàn Ènìyàn o, Ènìyàn yán Ènìyàn a b’ìdí yàn àn yán o Ènìyàn Òṣèlú, Ènìyàn ọ̀jẹ̀lú Ènìyàn tí ń f’agbáda gba agbada alágbẹ̀dẹ Ènìyàn tí…