Ní ojoojúmọ́ ayé mi ni mo máá ń ronú nípa ayé àwa ẹ̀dá, nípa àditú ayé tí ó ń fi ìgbà gbogbo ṣ’emí ní kàyéfì.…
Èyí ni ìtàn àròkọ kúkurú láti ẹnu Rasaq Malik Gbọ́lahàn. Bí ẹ̀yin naa fẹ wà ni àpèrè wa, ẹ kàn sí wa pẹ̀lú iṣẹ́ yin…
Inú wá dùn púpọ̀ láti kéde àtẹ̀jáde gidi ìwé wá —Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé. Iye: Ẹgbẹ̀rún Méjì àtààbọ̀ (N2,500) Ìfiṣọwọ́: Ọ̀fẹ́ ni a ó bá yín gbé…