Káṣílẹ́sí Pọlisì (Cash-Less Policy) | Akíntọ́lá Ismail Kọ́ládé
Ìlú kan gógó, Ilu òf’ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k’árówóná òdàbí k’álówó nílé k’álówó nílé gan-an […]
Ìlú kan gógó, Ilu òf’ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k’árówóná òdàbí k’álówó nílé k’álówó nílé gan-an […]
Ọmọ mí Mo bá wọn ná’jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́
Bí mo ṣe gbọ́ ìbéérè tí Dádì béèrè lọ́wọ́ mi, ṣe ni mo fi ẹ̀rín tó fẹ́ wú jáde lẹ́nu
Ṣèbí oun tí mo mọ̀n tí wọ́n má ń sọ ni pé òkùnkùn kìí bórí ìmọ́lẹ̀, pé irọ́ kìí jáwé
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí
Wón ní, Ikú ogun ló ń pa akíkanjú Ikú odò lo ń p’òmùwẹ̀ Ikú ẹwà ni wón ní ó ń