Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…
Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú àmọ́ irùngbọ̀n rẹ̀ funfun báláú.…
Mo ti pàdé ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìwọ̀n ọdún tí mo tì lò láyé, sùgbọ́n sàsà ni èyí tí ó nípa bíi bàbá Àmọ̀pé. Ọkùnrin mẹ́ta…
“Ẹ jẹ́ kí n gé e jẹ o! Olè, aláìnítẹ̀ẹ́lọ́rùn, ọ̀kánjúwà!” Igbe yìí ni mò ń gbọ́ bí mo ṣe dé ẹnu ọ̀nà àbáwọlé ibùgbé…