Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À'teku, à'teye, àti omo adáríhurun ọ̀rọ̀ ilé ayeé…
Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí Abíọdún. Orí rẹ pé púpò;…