Ṣóo wo iwájú tóò r’ẹ́nìkan O w’ẹ̀yìn wò, óò r’éèyàn L’ọ́tùn-ún l’ósì, ilẹ̀ tẹ́ lọ bẹẹrẹ Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, o ní ikú ló kàn Ọjọ́ a…
ÀKỌ́LÉ :onílù OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà àkìrẹ́líkì ỌDÚN : 2018 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá SÍTÁILÌ: Araism (iṣẹ́ ọnà). ÀKỌ́LÉ :Agbè Ẹmu OHUN ÈLÒ : Òwú sílíkì.…