Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Tags archive: Atelewo

Home /Tag:Atelewo
Àpilẹ̀kọ

Ọ̀làjú Dé | Abọ́lájí ọmọ Babalọlá

July 12, 2018 0

Yorùbá bọ̀ wón ní báyé ba ń yí kámáa bá’yé yí, bí ìgbà báńyí ká máa bá ìgbà yi torí ẹni tí kò bá bágbàyí…

Ewì

Ẹ wa̒a̒ wẹ̀si̒n ara̒ ìbàdaǹ! | Fẹ́mi Àjàkáyé

July 12, 2018 0

Lààlá òfò La̒a̒làṣe̒ asa̒n Gẹ̀gẹ̀sì òsì. Gàgàrà ìyà Gẹgẹrẹ  la̒sa̒n, Òfu̒ùtù fẹ̒ètẹ̀ A̒a̒sà ti̒ ò ni̒ ka̒nhu̒n. Ki̒ni ka̒ ti se’le̒ Ti̒sà yi̒ si̒? Ile̒…

Ìtàn

Àyọkà Láti Inú Dáyáárì Sálù Jẹ́nwítèmi | ‘Gbénga Adéọba

July 12, 2018 0

Ọdún tí ọwọ́ tẹ Ẹ́fáansì ajínigbé Ọjọ́bọ̀. Ọjọ́ kẹ̀jọ, Oṣù Agẹmọ. Gbogbo bí wọ́n ṣe nkígbe níle Kejì, hun ò kúkú yọjú. Wọ́n ni àgbà…

Ìròyìn

Ra ìwé Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé / Buy Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé Hardcopy Book

April 11, 2018 0

Inú wá dùn púpọ̀ láti kéde àtẹ̀jáde gidi ìwé wá —Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé. Iye: Ẹgbẹ̀rún Méjì àtààbọ̀ (N2,500) Ìfiṣọwọ́: Ọ̀fẹ́ ni a ó bá yín gbé…

Ìròyìn

ÀTẸ́LẸWỌ PÉLÉBÉ TI JÁDE/ ÀTẸ́LẸWỌ PÉLÉBÉ IS OUT!

February 8, 2018 0

Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù ló yọ Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù ló yọ Àṣẹ̀ṣẹ̀dé ọṣù, wọ́n lo ṣ’ara bíntín Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù…

Posts navigation

prev 1 … 6 7

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Oguso
  • Orin
  • Ọ̀rọ̀ Ìlú
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized