Yorùbá bọ̀ wón ní báyé ba ń yí kámáa bá’yé yí, bí ìgbà báńyí ká máa bá ìgbà yi torí ẹni tí kò bá bágbàyí…
Lààlá òfò La̒a̒làṣe̒ asa̒n Gẹ̀gẹ̀sì òsì. Gàgàrà ìyà Gẹgẹrẹ la̒sa̒n, Òfu̒ùtù fẹ̒ètẹ̀ A̒a̒sà ti̒ ò ni̒ ka̒nhu̒n. Ki̒ni ka̒ ti se’le̒ Ti̒sà yi̒ si̒? Ile̒…
Ọdún tí ọwọ́ tẹ Ẹ́fáansì ajínigbé Ọjọ́bọ̀. Ọjọ́ kẹ̀jọ, Oṣù Agẹmọ. Gbogbo bí wọ́n ṣe nkígbe níle Kejì, hun ò kúkú yọjú. Wọ́n ni àgbà…
Inú wá dùn púpọ̀ láti kéde àtẹ̀jáde gidi ìwé wá —Àtẹ́lẹwọ́ Pélébé. Iye: Ẹgbẹ̀rún Méjì àtààbọ̀ (N2,500) Ìfiṣọwọ́: Ọ̀fẹ́ ni a ó bá yín gbé…
Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù ló yọ Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù ló yọ Àṣẹ̀ṣẹ̀dé ọṣù, wọ́n lo ṣ’ara bíntín Àtẹ́lẹwọ́ yọ wọ́n ṣe b’oṣù…