Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú, Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn láti máa ge kúrú sí…
Òpóǹló ni mo wà tí mo ti máa ń gbọ́ nípa ìlú Èkó. Oríṣiríṣi ni atilẹ̀ máa ń gbọ́ ni ìgbà náà. Àwọn kan àtilẹ̀…
Mo ti pàdé ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìwọ̀n ọdún tí mo tì lò láyé, sùgbọ́n sàsà ni èyí tí ó nípa bíi bàbá Àmọ̀pé. Ọkùnrin mẹ́ta…