Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À'teku, à'teye, àti omo adáríhurun ọ̀rọ̀ ilé ayeé…
Ojú lọ̀rọ́ wà, ètè kọ́ Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lẹnu Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lètè Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lẹnu –Èdè ẹnu fun ìlù u…