Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń Bèrè nípa kíkorò tí ewúro…
Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí, mo le sòótọ́ dòbu Ajá…
ÀKỌ́LÉ :Orí OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà Ọìlì ỌDÚN : 2014/2015 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá GBÓLÓHÙN IṢẸ́ NÁÀ– Òrìṣà pàtàkì ni a mọ orí sí láàrín ọkanlélúgba irúnmọlẹ̀,…