Ìtakúrọsọ̀ láàrín Náírà àti Kọ́bọ̀ | Foláşadé ọmọ Oláòníye
Ó kúkú ti pẹ́ tí Náírà ti ń gbọ́ nípa Kọ́bọ̀. Kódà ìtàn sọ fun u pé gẹ́lẹ́ tí Náírà […]
Ó kúkú ti pẹ́ tí Náírà ti ń gbọ́ nípa Kọ́bọ̀. Kódà ìtàn sọ fun u pé gẹ́lẹ́ tí Náírà […]
ÀKỌ́LÉ :Orí OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà Ọìlì ỌDÚN : 2014/2015 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá GBÓLÓHÙN IṢẸ́ NÁÀ– Òrìṣà pàtàkì ni a mọ
[youtube]https://youtu.be/5-dJkuC3VSw[/youtube] Èyí ni ìtàn àròkọ kúkurú láti ẹnu Rasaq Malik Gbọ́lahàn. Bí ẹ̀yin naa fẹ wà ni àpèrè wa, ẹ
ÀKỌ́LÉ :onílù OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà àkìrẹ́líkì ỌDÚN : 2018 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá SÍTÁILÌ: Araism (iṣẹ́ ọnà). ÀKỌ́LÉ :Agbè Ẹmu
[youtube]https://youtu.be/TzyREDaP3pU[/youtube] Ènìyàn Ènìyàn o, Ènìyàn yán Ènìyàn a b’ìdí yàn àn yán o Ènìyàn Òṣèlú, Ènìyàn ọ̀jẹ̀lú Ènìyàn tí ń
[youtube]https://youtu.be/lNHx552ToeQ[/youtube] Rasaq Malik jẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́ gboyè nínú ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì ní Ilé Ìwé gíga fásitì èyí tí o fì’dí
Ẹ wí f’ẹ́ni tí ń sáré owó Pélé t’ówó kọ a máa wọ́ Ẹ rò f’ẹni tí ń kànlẹ̀kùn ọlà
È̩RÍN ÀRÍNTÀKÌTÌ L’ÉKÌTÌ Ìpínlè̩ Èkìtì jé̩ ò̩kan pàtàkì lára àwo̩n ìpínlè̩ t íÌjo̩ba Ológun dásílè̩ ní 1996 lábé̩ ìs̩è jo̩ba
ÒWE Ọsán já ọrún d’ọ̀pá. ÀKÍYÈSÍ *Ọsán:- ohun èlò tí a fi ún se ǹkan ìjà tí a mò sí
Ojú lọ̀rọ́ wà, ètè kọ́ Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lẹnu Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lètè Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lẹnu