Àpilẹ̀kọ Kọ̀lọ̀rọ̀sí | Khadijah Ọlájùmọ̀kẹ́ Kọ́lápọ̀ August 3, 2020 0 Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…