Àtẹ́lẹwọ́

Ìfipábánilòpọ̀ (ìtàn) Rasaq Malik | Ẹgbẹ́ Àtẹ́lẹwọ́

[youtube]https://youtu.be/5-dJkuC3VSw[/youtube]

Èyí ni ìtàn àròkọ kúkurú láti ẹnu Rasaq Malik Gbọ́lahàn. Bí ẹ̀yin naa fẹ wà ni àpèrè wa, ẹ kàn sí wa pẹ̀lú iṣẹ́ yin ní egbeatelewo@gmail.com tabi kí ẹ lọ sí línkì yìí – https://www.atelewo.org/igbawole/. Ẹ kàn sí www.atelewo.org láti ka awọn iṣẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá to múnádóko.