Àpilẹ̀kọ Ewì ní ìrántí Adébáyọ̀ Fálétí, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, àti Ọládẹ̀jọ Òkédìjí |Kọ́dáolú Tolúlọpẹ́ June 20, 2020 0 Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri sọ Ta ń mọ bi…