Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá olóṣù mẹ́ta tí a gbé kalẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára Zoom fún àwọn ọmọdé tí ọjọ́ orí wọn kò ju ọdún mẹ́tàdínlógún lọ. Ẹ̀kọ́ yìí yóò kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní álífábẹ́ẹ̀tì èdè Yorùbá, àmì ohùn, kíkọ àti kíkà Yorùbá, òunkà Yorùbá, ìsòrí gbólóhùn, lítírésọ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọ yín darapọ̀ mọ́ wa, kí á le bá gbé àṣà àti ìṣe Yorùbá lárugẹ. Kí èdè Yorùbá má parun, àjùmọ̀ṣe gbogbo wa ni.

The 3-Month Online Beginner’s class will introduce your kids to the rudiments of Yorùbá language. It will focus on Yoruba alphabets, àmì ohùn (tonal marks), parts of speech, counting and the construction of error-free Yoruba sentences. It will foreground reading and writing in Yorùbá and pay close attention to Yorùbá literature and games.
The class promises to be fun and educative.

Duration/Àkókò

3 months /Oṣù Mẹ́ta

3 sessions of 2 hours each (per week).

Age Range/Ọjọ́ Orí Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́

17 years and below. Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún wá sí lẹ̀.

Platform/Àpèrè

Zoom

Fee/Owó

30 USD | N10,000 Monthly /l’óṣooṣù

Payment/Ìsanwó

ATELEWO CULTURE AND LANGUAGE SERVICES
1021878832
United Bank for Africa

atelewo.org@gmail.com

After payment, send a screenshot evidence to 2347061282516 on WhatsApp to confirm your registration.

For more enquiries, mail atelewo.org@gmail.com or via WhatsApp below.