Èyí ni ẹ̀kọ́ Àmì Èdè Yorùbá ọlọ́sẹ̀ mẹ́ta tí a gbé kalẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára Zoom. Ẹ̀kọ́ yìí yóò kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní álífábẹ́ẹ̀tì èdè Yorùbá, àmì ohùn, kíkọ àti kíkà Yorùbá lórí ẹ̀rọ alágbèéká àti Kọ̀mpútà.

This is a 3-week Online Yorùbá Diacritics class that will take place on Zoom. The class will focus on Yoruba alphabets, àmì ohùn (tonal marks), reading and writing Yorùbá fluently on mobile and PC.

Duration/Àkókò

3 weekends /Òpin Ọ̀sẹ̀ Mẹ́ta

Platform/Àpèrè

Zoom

Fee/Owó

10 USD | N5,000 /Ẹgbèrún Márùn-ún Náírà

Deadline/Gbèdẹ́kun

July 31/ Ọgbọ̀n ọjọ́ ó lékan, Oṣù Keje

Payment/Ìsanwó

ATELEWO CULTURE AND LANGUAGE SERVICES
1021878832
United Bank for Africa

Or Pay Via Paystack Below

https://paystack.com/pay/amiyorubaclass

After payment, send a screenshot evidence to egbeatelewo@gmail.com or to 2347061282516 via WhatsApp to confirm your registration.