ÀTẸ́LẸWỌ́ ṣe àgbékalẹ̀ Ayẹyẹ Àyájọ́ Ọjọ́ Èdè Abínibí Pẹ̀lú Ayẹyẹ Ọjọ́ Ẹ̀bùn fún Ìdíje Ìwé Kíkọ Ti Ọdún 2024

Àkòrí: Èdè Ni Òpó Ìmọ̀
Gbàgede Ètò: BNI Youth Centre, First Floor, U&I Building, University of Ibadan.
Ọjọ́: Ọjọ́ kẹsàn-án, Oṣù Kẹta Ọdún 2024

Ẹ fi orúkọ sílẹ̀ láti darapọ̀ mọ́ wa.

For Àtìlẹyìn àti ìwádìí, ẹ kàn sí 07061282516, 08169864345.

International Mother Language Day 2024

ÀTẸ́LẸWỌ́ presents 2024 International Mother Language Day Celebration featuring

  • ÀTẸ́LẸWỌ́ PRIZE FOR YORÙBÁ LITERATURE 2024 AWARD CEREMONY
  • Phase 3 Launching of Ògbóntarigì Documentary Project on Pa Gabriel Ọmọ́táyọ̀ Oníbọnòjé

Theme: Èdè Ni Òpó Ìmọ̀
Venue: BNI Youth Centre, First Floor, U&I Building, University of Ibadan.

Date: March 9, 2024

Register to join us.

For Support & Partnership, call 07061282516, 08169864345.